AfrobeatsHot SongsSongs

Seyi Vibez Fuji Interlude MP3 Download & Lyrics

Spread the love

“Fuji Interlude” is a captivating track from Nigerian singer Seyi Vibez’s music collection. The song is a fusion of two popular Nigerian music genres, Fuji and Afrobeats, with Seyi Vibez’s unique sound and style shining through.

The “Fuji Interlude” features Seyi Vibez’s soulful vocals, accompanied by a vibrant beat that blends traditional Fuji percussion with modern Afrobeats sounds. The lyrics of the song express Seyi Vibez’s love for music and the important role it has played in his life. The “Fuji Interlude” is a standout track in Seyi Vibez’s music repertoire, showcasing his versatility and creativity as an artist. It’s a must-listen for fans of Nigerian music and those who appreciate the fusion of different genres to create something truly unique.

Download Fuji Interlude

Fuji Interlude Lyrics

Mo kí rá fun Ọba Ilayi
Tí o dójú tí mí o
Ko sí ẹní t’omọ là t’oko
Ẹ’mí náà àá d’eyán o
Ẹlẹ’dàá mí má jẹ rá m’àyé
Ehhh, mo tí dé bí mo ṣe ńdé o
Mo tún-tún gbé èrè mí dé o
Oluwaloseyi o
Ẹní fẹ ná mí owó o kó wa bí

Bisi-Bisi, ní wo yí? (ní wo yí?)
Sexy Mama, ní mà yí (ní mà yí)
Ṣé o má lo mọ singer yí (singer yí)
Everyday ká ní bà yí (ní bà yí)

Àwọn kàn tí kó ṣí wàju, wọn tún kó’rin ni sí yín o
Àwọn kàn wá pọ níwájú, Alabi o wesẹ mí o
Bá mí kí Bàbá Balo
Ẹní jẹun lo má yo

Ìkú má pá brother mí o
Kí ikú má pá maga mí o
K’emí r’owó ṣayé
Wọn gbọ mí ní Germany dé’Ibafo
Kó mọ gbà t’owó kú wazo o
Àwọn girl tí wo Palazzo

Óyà, baby mí, wá jo
O tí mọ p’owó dé kún’lé o
50 Million ẹ-ku wazo
Money dey tí má ká o
Seyi, Malaika
Àwọn kán fẹ gará ní massion o

When I say óyá-óyà, let’s dance
Óyá-óyà, jẹ ká jo
Óyá-óyà, let us dance
Jẹ ká lo s’agbo Loseyi oo

Óyá-óyà, let’s dance
Óyá-óyà, jẹ ká jo
Óyá-óyà, let us dance
Jẹ ká lọ s’agbo Loseyi oo

Óyá-óyà, let’s dance
Óyá-óyà, jẹ ká jo
Óyá-óyà, let us dance
Jẹ ká lọ s’agbo Loseyi oo

Óyá-óyà, let’s dance
Óyá-óyà, jẹ ká jo
Óyá-óyà, let us dance
Jẹ ká lọ s’agbo Loseyi oo

Woo!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Worth reading...
Nathaniel Bassey – Adonai MP3 Download